Orin Dafidi 90:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Aadọrin ọdún ni ọjọ́ ayé wa;pẹlu ipá a lè tó ọgọrin;sibẹ gbogbo rẹ̀ jẹ́ kìkì làálàá ati ìyọnu;kíá, ayé wa á ti dópin, ẹ̀mí wa á sì fò lọ.

Orin Dafidi 90

Orin Dafidi 90:2-17