Orin Dafidi 9:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ìwọ ni o fi ìdí ẹ̀tọ́ mi múlẹ̀, tí o sì dá mi láre;ìwọ ni o jókòó lórí ìtẹ́, o sì ṣe ìdájọ́ òdodo.

Orin Dafidi 9

Orin Dafidi 9:1-7