Orin Dafidi 9:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé OLUWA kò ní fi ìgbà gbogbo gbàgbé àwọn aláìní,bẹ́ẹ̀ ni ìrètí àwọn talaka kò ní já sí òfo títí lae.

Orin Dafidi 9

Orin Dafidi 9:10-20