Orin Dafidi 89:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ò ń jọba lórí òkun tí ń ru;nígbà tí ìgbì rẹ̀ bá ru sókè, ìwọ ni ò ń mú kí ó rọlẹ̀.

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:7-11