Orin Dafidi 89:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nisinsinyii inú rẹ ti ru sí ẹni àmì òróró rẹ;o ti ta á nù,o sì ti kọ̀ ọ́ sílẹ̀.

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:29-40