Orin Dafidi 89:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Arọmọdọmọ rẹ̀ ni yóo máa jọba títí lae;ìtẹ́ rẹ̀ yóo sì máa bẹ níwọ̀n ìgbà tí ojú ọ̀run bá ń bẹ.

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:28-34