Orin Dafidi 89:21 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ọwọ́ agbára mi lè máa gbé e ró títí lae,kí ọwọ́ mi sì máa fún un ní okun.

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:12-31