Orin Dafidi 89:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Òdodo ati ẹ̀tọ́ ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ;ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ati òtítọ́ ń lọ ṣiwaju rẹ.

Orin Dafidi 89

Orin Dafidi 89:6-22