Orin Dafidi 88:8 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti mú kí àwọn ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mi fi mí sílẹ̀;mo sì ti di ẹni ìríra lọ́dọ̀ wọn:mo wà ninu àhámọ́, n kò sì lè jáde;

Orin Dafidi 88

Orin Dafidi 88:3-9