Orin Dafidi 88:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ìgbà èwe mi ni a tí ń jẹ mí níyà,tí mo sì fẹ́rẹ̀ kú,mo ti rí ìjẹníyà rẹ tí ó bani lẹ́rù;agara sì ti dá mi.

Orin Dafidi 88

Orin Dafidi 88:7-18