Orin Dafidi 88:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé a lè rí iṣẹ́ ìyanu rẹ ninu òkùnkùn ikú?Àbí ìrànlọ́wọ́ ìgbàlà rẹ wà ní ilẹ̀ àwọn tí a ti gbàgbé?

Orin Dafidi 88

Orin Dafidi 88:6-17