Orin Dafidi 86:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí o dá ni yóo wá,OLUWA, wọn óo máa forí balẹ̀ níwájú rẹ:wọn óo sì máa yin orúkọ rẹ lógo.

Orin Dafidi 86

Orin Dafidi 86:1-16