Orin Dafidi 86:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé olóore ni ọ́, OLUWA,o máa ń dárí jini;ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ sì pọ̀ sí gbogbo àwọn tí ń ké pè ọ́.

Orin Dafidi 86

Orin Dafidi 86:4-10