Orin Dafidi 86:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Dá ẹ̀mí mi sí nítorí olùfọkànsìn ni mí;gba èmi iranṣẹ rẹ tí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ là;ìwọ ni Ọlọrun mi.

Orin Dafidi 86

Orin Dafidi 86:1-6