Orin Dafidi 85:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Tún mú wa bọ̀ sípò, Ọlọrun Olùgbàlà wa;dáwọ́ inú tí ń bí ọ sí wa dúró.

5. Ṣé o óo máa bínú sí wa títí lae ni?Ṣé ibinu rẹ yóo máa tẹ̀síwájú láti ìran dé ìran ni?

6. Ṣé o ò ní tún sọ wá jí ni,kí àwọn eniyan rẹ lè máa yọ̀ ninu rẹ?

Orin Dafidi 85