Orin Dafidi 84:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ayọ̀ ń bẹ fún gbogbo àwọn tí ó fi ọ́ ṣe agbára wọn,tí ìrìn àjò sí Sioni jẹ wọ́n lógún.

Orin Dafidi 84

Orin Dafidi 84:1-10