Orin Dafidi 83:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n pète àrékérekè sí àwọn eniyan rẹ;wọ́n sì gbìmọ̀ pọ̀ sí àwọn tí ó sá di ọ́.

Orin Dafidi 83

Orin Dafidi 83:1-5