Orin Dafidi 83:17-18 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Jẹ́ kí ojú tì wọ́n, kí ìdààmú dé bá wọn títí lae,kí wọn sì ṣègbé ninu ìtìjú.

18. Jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ìwọ nìkan,tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ OLUWA,ni Ọ̀gá Ògo lórí gbogbo ayé.

Orin Dafidi 83