Orin Dafidi 83:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Da ìtìjú bò wọ́n,kí wọn lè máa wá ọ kiri, OLUWA.

17. Jẹ́ kí ojú tì wọ́n, kí ìdààmú dé bá wọn títí lae,kí wọn sì ṣègbé ninu ìtìjú.

18. Jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ìwọ nìkan,tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ OLUWA,ni Ọ̀gá Ògo lórí gbogbo ayé.

Orin Dafidi 83