Orin Dafidi 81:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín,tí ó mu yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti.Ẹ ya ẹnu yín dáradára, n óo sì bọ yín ní àbọ́yó.

Orin Dafidi 81

Orin Dafidi 81:2-14