Orin Dafidi 81:1-3 BIBELI MIMỌ (BM) Ẹ kọ orin sókè sí Ọlọrun, agbára wa;ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọrun Jakọbu. Ẹ dárin, ẹ lu samba