Orin Dafidi 8:8-9 BIBELI MIMỌ (BM)

8. àwọn ẹyẹ ojú ọrun, àwọn ẹja inú òkun,ati gbogbo nǹkan tí ó ń lúwẹ̀ẹ́ ninu òkun.

9. OLUWA, Oluwa wa,orúkọ rẹ níyìn pupọ ní gbogbo ayé!

Orin Dafidi 8