Orin Dafidi 79:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ti pẹ́ tó, OLUWA?Ṣé títí ayé ni o óo máa bínú ni?Àbí owú rẹ yóo máa jó bí iná?

Orin Dafidi 79

Orin Dafidi 79:1-9