Orin Dafidi 79:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ìkérora àwọn ìgbèkùn wá sí ọ̀dọ̀ rẹ;gẹ́gẹ́ bí agbára ńlá rẹ,dá àwọn tí a dájọ́ ikú fún sí.

Orin Dafidi 79

Orin Dafidi 79:1-13