Orin Dafidi 78:71 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú un níbi tí ó ti ń tọ́jú àwọn aguntantí ó lọ́mọ lẹ́yìn,kí ó lè máa tọ́jú àwọn ọmọ Jakọbu, eniyan rẹ̀,àní àwọn ọmọ Israẹli, eniyan ìní rẹ̀.

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:66-72