Orin Dafidi 78:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n yipada, wọ́n sì hu ìwà ọ̀dàlẹ̀bíi ti àwọn baba ńlá wọn;wọn kò ṣe é gbẹ́kẹ̀lé, wọ́n dàbí ọfà tí ó tẹ̀.

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:47-58