Orin Dafidi 78:51 BIBELI MIMỌ (BM)

O kọlu gbogbo àkọ́bí wọn ní ilẹ̀ Ijipti,àní, gbogbo àrẹ̀mọ ninu àgọ́ àwọn ọmọ Hamu.

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:47-55