Orin Dafidi 78:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi ìlànà lélẹ̀ fún ìdílé Jakọbu;ó gbé òfin kalẹ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli.Ó pa á láṣẹ fún àwọn baba ńlá wa,pé kí wọ́n fi kọ́ àwọn ọmọ wọn.

Orin Dafidi 78

Orin Dafidi 78:1-7