Orin Dafidi 77:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi, mo wá OLUWA;ní òru, mo tẹ́wọ́ adura láìkáàárẹ̀,ṣugbọn n kò rí ìtùnú.

Orin Dafidi 77

Orin Dafidi 77:1-9