Orin Dafidi 76:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa ìbáwí rẹ, Ọlọrun Jakọbu,ati ẹṣin, ati ẹni tó gun ẹṣin,gbogbo wọn ló ṣubú lulẹ̀, tí wọn kò sì lè mira.

Orin Dafidi 76

Orin Dafidi 76:1-12