Orin Dafidi 74:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n pinnu lọ́kàn wọn pé, “A óo bá wọn kanlẹ̀ patapata.”Wọ́n dáná sun gbogbo ilé ìsìn Ọlọrun tí ó wà ní ilẹ̀ náà.

Orin Dafidi 74

Orin Dafidi 74:7-16