Orin Dafidi 74:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọ̀tá rẹ bú ramúramù ninu ilé ìsìn rẹ;wọ́n ta àsíá wọn gẹ́gẹ́ bí àmì ìṣẹ́gun.

Orin Dafidi 74

Orin Dafidi 74:1-12