Orin Dafidi 74:18 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ranti pé àwọn ọ̀tá ń fi ọ́ ṣe yẹ̀yẹ́;àwọn òmùgọ̀ eniyan sì ń fi orúkọ rẹ ṣe ẹlẹ́yà.

Orin Dafidi 74

Orin Dafidi 74:12-23