Orin Dafidi 74:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, ìwọ ṣá ni ọba wa láti ìbẹ̀rẹ̀ wá;ìwọ ni o máa ń gbà wá là láàrin gbogbo orílẹ̀-èdè.

Orin Dafidi 74

Orin Dafidi 74:9-18