Jẹ́ kí ó máa gbèjà àwọn eniyan tí ìyà ń jẹ;kí ó máa gba àwọn ọmọ talaka sílẹ̀;kí ó sì rún àwọn aninilára wómúwómú.