Orin Dafidi 72:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé a máa gba talaka tí ó bá ké pè é sílẹ̀;a sì máa gba àwọn tí ìyà ń jẹ sílẹ̀,ati àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́.

Orin Dafidi 72

Orin Dafidi 72:7-19