Orin Dafidi 72:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọba Taṣiṣi ati àwọn ọba erékùṣù gbogboyóo máa san ìṣákọ́lẹ̀ fún un;àwọn ọba Ṣeba ati ti Seba yóo máa mú ẹ̀bùn wá.

Orin Dafidi 72

Orin Dafidi 72:1-16