Orin Dafidi 71:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ìwọ OLUWA, ni ìrètí mi,OLUWA, Ọlọrun mi, ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀lé láti ìgbà èwe mi.

Orin Dafidi 71

Orin Dafidi 71:1-14