Orin Dafidi 71:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, láti ìgbà èwe mi ni o ti kọ́ mi,títí di òní ni mo sì ń polongo iṣẹ́ ìyanu rẹ,

Orin Dafidi 71

Orin Dafidi 71:16-24