Orin Dafidi 71:15 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo máa ṣírò iṣẹ́ rere rẹ,n óo máa ròyìn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ tọ̀sán-tòru,nítorí wọ́n pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí n kò lè mọ iye wọn.

Orin Dafidi 71

Orin Dafidi 71:6-22