Orin Dafidi 70:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ojú ti gbogbo àwọn tí wọn fẹ́ gba ẹ̀mí mikí ìdàrúdàpọ̀ bá wọn;jẹ́ kí á lé àwọn tí ń wá ìpalára mi pada sẹ́yìn,kí wọn sì tẹ́.

Orin Dafidi 70

Orin Dafidi 70:1-5