Orin Dafidi 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ló ń ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè ayé;dá mi láre, OLUWA, gẹ́gẹ́ bí òdodo mi ati ìwà pípé mi.

Orin Dafidi 7

Orin Dafidi 7:1-11