Orin Dafidi 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, fi ibinu dìde!Gbéra, kí o bá àwọn ọ̀tá mi jà ninu ìrúnú wọn;jí gìrì, Ọlọrun mi; ìwọ ni o ti fi ìlànà òdodo lélẹ̀.

Orin Dafidi 7

Orin Dafidi 7:1-13