Orin Dafidi 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọn kò bá yipada, Ọlọrun yóo pọ́n idà rẹ̀;ó ti tẹ ọrun rẹ̀, ó sì ti fi ọfà lé e.

Orin Dafidi 7

Orin Dafidi 7:8-16