Orin Dafidi 69:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, o mọ ìwà òmùgọ̀ mi,àwọn àṣìṣe mi kò sì fara pamọ́ fún ọ.

Orin Dafidi 69

Orin Dafidi 69:1-9