Orin Dafidi 69:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Ọlọrun yóo gba Sioni là;yóo sì tún àwọn ìlú Juda kọ́;àwọn iranṣẹ rẹ̀ yóo máa gbé inú rẹ̀,yóo sì di tiwọn.

Orin Dafidi 69

Orin Dafidi 69:27-36