Orin Dafidi 69:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sọkún títí àárẹ̀ mú mi,ọ̀nà ọ̀fun mi gbẹ,ojú mi sì di bàìbàì,níbi tí mo ti dúró, tí mò ń wo ojú ìwọ Ọlọrun mi.

Orin Dafidi 69

Orin Dafidi 69:1-8