Orin Dafidi 69:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ojú wọn ṣú,kí wọn má lè ríran;kí gbogbo ara wọn sì máa gbọ̀n rìrì.

Orin Dafidi 69

Orin Dafidi 69:14-30