Orin Dafidi 69:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀gàn ti mú kí inú mi bàjẹ́,tóbẹ́ẹ̀ tí ọkàn mi rẹ̀wẹ̀sìmò ń retí àánú ṣugbọn kò sí;mò ń retí olùtùnú, ṣugbọn n kò rí ẹnìkan.

Orin Dafidi 69

Orin Dafidi 69:16-23