Orin Dafidi 69:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Dá mi lóhùn, OLUWA, nítorí ìfẹ́ rẹtí kì í yẹ̀ dára;fojú rere wò mí, gẹ́gẹ́ bí ọpọlọpọ àánú rẹ.

Orin Dafidi 69

Orin Dafidi 69:11-26